1
O. Daf 44:8
Bibeli Mimọ
Niti Ọlọrun li awa nkọrin iyìn li ọjọ gbogbo, awa si nyìn orukọ rẹ lailai.
Compare
Explore O. Daf 44:8
2
O. Daf 44:6-7
Nitoriti emi kì yio gbẹkẹle ọrun mi, bẹ̃ni idà mi kì yio gbà mi. Ṣugbọn iwọ li o ti gbà wa lọwọ awọn ọta wa, iwọ si ti dojutì awọn ti o korira wa.
Explore O. Daf 44:6-7
3
O. Daf 44:26
Dide fun iranlọwọ wa, ki o si rà wa pada nitori ãnu rẹ.
Explore O. Daf 44:26
Home
Bible
Plans
Videos