1
O. Daf 37:4
Bibeli Mimọ
Ṣe inu-didùn si Oluwa pẹlu, on o si fi ifẹ inu rẹ̀ fun ọ.
Compare
Explore O. Daf 37:4
2
O. Daf 37:5
Fi ọ̀na rẹ̀ le Oluwa lọwọ; gbẹkẹle e pẹlu; on o si mu u ṣẹ.
Explore O. Daf 37:5
3
O. Daf 37:7
Iwọ simi ninu Oluwa, ki o si fi sũru duro dè e; máṣe ikanra nitori ẹniti o nri rere li ọ̀na rẹ̀, nitori ọkunrin na ti o nmu èro buburu ṣẹ.
Explore O. Daf 37:7
4
O. Daf 37:3
Gbẹkẹle Oluwa, ki o si ma ṣe rere; ma gbe ilẹ na, ki o si ma huwa otitọ.
Explore O. Daf 37:3
5
O. Daf 37:23-24
A ṣe ìlana ẹsẹ enia lati ọwọ Oluwa wá: o si ṣe inu didùn si ọ̀na rẹ̀. Bi o tilẹ ṣubu, a kì yio ta a nù kuro patapata; nitoriti Oluwa di ọwọ rẹ̀ mu.
Explore O. Daf 37:23-24
6
O. Daf 37:6
Yio si mu ododo rẹ jade bi imọlẹ, ati idajọ rẹ bi ọsángangan.
Explore O. Daf 37:6
7
O. Daf 37:8
Dakẹ inu-bibi, ki o si kọ̀ ikannu silẹ: máṣe ikanra, ki o má ba ṣe buburu pẹlu.
Explore O. Daf 37:8
8
O. Daf 37:25
Emi ti wà li ewe, emi si dagba; emi kò ti iri ki a kọ̀ olododo silẹ, tabi ki iru-ọmọ rẹ̀ ki o ma ṣagbe onjẹ.
Explore O. Daf 37:25
9
O. Daf 37:1
MÁṢE ikanra nitori awọn oluṣe-buburu, ki iwọ ki o máṣe ilara nitori awọn oniṣẹ ẹ̀ṣẹ.
Explore O. Daf 37:1
Home
Bible
Plans
Videos