1
Hab 2:2-3
Bibeli Mimọ
Oluwa si da mi lohùn, o si wipe, Kọ iran na, ki o si hàn a lara wàlã, ki ẹniti nkà a, le ma sare. Nitori iran na jẹ ti igbà kan ti a yàn, yio ma yára si igbẹhìn, kì yio si ṣeke, bi o tilẹ̀ pẹ, duro dè e, nitori ni dide, yio de, kì yio pẹ.
Compare
Explore Hab 2:2-3
2
Hab 2:14
Nitoriti aiye yio kún fun ìmọ ogo Oluwa, bi omi ti bò okun.
Explore Hab 2:14
3
Hab 2:20
Ṣugbọn Oluwa mbẹ ninu tempili rẹ̀ mimọ́; jẹ ki gbogbo aiye pa rọ́rọ niwaju rẹ̀.
Explore Hab 2:20
Home
Bible
Plans
Videos