1
Oni 1:18
Bibeli Mimọ
Nitoripe ninu ọgbọ́n pupọ ni ibinujẹ pupọ wà, ẹniti o si nsọ ìmọ di pupọ, o nsọ ikãnu di pupọ.
Compare
Explore Oni 1:18
2
Oni 1:9
Ohun ti o wà, on ni yio si wà; ati eyiti a ti ṣe li eyi ti a o ṣe; kò si ohun titun labẹ õrùn.
Explore Oni 1:9
3
Oni 1:8
Ọ̀rọ gbogbo kò to; enia kò le sọ ọ: iran kì isu oju, bẹ̃li eti kì ikún fun gbigbọ́.
Explore Oni 1:8
4
Oni 1:2-3
Asan inu asan, oniwasu na wipe, asan inu asan; gbogbo rẹ̀ asan ni! Ere kili enia jẹ ninu gbogbo lãla rẹ̀ ti o ṣe labẹ õrùn?
Explore Oni 1:2-3
5
Oni 1:14
Mo ti ri iṣẹ gbogbo ti a nṣe labẹ õrùn; si kiyesi i, asan ni gbogbo rẹ̀ ati imulẹmofo.
Explore Oni 1:14
6
Oni 1:4
Iran kan lọ, iran miran si bọ̀: ṣugbọn aiye duro titi lai.
Explore Oni 1:4
7
Oni 1:11
Kò si iranti ohun iṣaju; bẹ̃ni iranti kì yio si fun ohun ikẹhin ti mbọ̀, lọdọ awọn ti mbọ̀ ni igba ikẹhin.
Explore Oni 1:11
8
Oni 1:17
Nigbati mo fi aiya mi si ati mọ̀ ọgbọ́n, ati lati mọ̀ isinwin ati iwère: nigbana ni mo mọ̀ pe, eyi pẹlu jẹ imulẹmofo.
Explore Oni 1:17
Home
Bible
Plans
Videos