1
Iṣe Apo 16:31
Bibeli Mimọ
Nwọn si wi fun u pe, Gbà Jesu Kristi Oluwa gbọ́, a o si gbà ọ là, iwọ ati awọn ará ile rẹ pẹlu.
Compare
Explore Iṣe Apo 16:31
2
Iṣe Apo 16:25-26
Ṣugbọn larin ọganjọ Paulu on Sila ngbadura, nwọn si nkọrin iyìn si Ọlọrun: awọn ara tubu si ntẹti si wọn. Lojiji iṣẹlẹ nla si ṣẹ̀, tobẹ̃ ti ipilẹ ile tubu mi titi: lọgan gbogbo ilẹkun si ṣí, ìde gbogbo wọn si tu silẹ.
Explore Iṣe Apo 16:25-26
3
Iṣe Apo 16:30
O si mu wọn jade, o ni, Alàgba, kini ki emi ki o ṣe ki ng le là?
Explore Iṣe Apo 16:30
4
Iṣe Apo 16:27-28
Nigbati onitubu si tají, ti o si ri pe, awọn ikẹkun tubu ti ṣí silẹ, o fà idà rẹ̀ yọ, o si fẹ pa ara rẹ̀, o ṣebi awọn ara tubu ti sá lọ. Ṣugbọn Paulu kọ kàrá, wipe, Máṣe pa ara rẹ lara: nitori gbogbo wa mbẹ nihinyi.
Explore Iṣe Apo 16:27-28
Home
Bible
Plans
Videos