1
I. A. Ọba 11:4
Bibeli Mimọ
O si ṣe, nigbati Solomoni di arugbo, awọn obinrin rẹ̀ yi i li ọkàn pada si ọlọrun miran: ọkàn rẹ̀ kò si ṣe dede pẹlu Oluwa Ọlọrun rẹ̀, gẹgẹ bi ọkàn Dafidi, baba rẹ̀.
Compare
Explore I. A. Ọba 11:4
2
I. A. Ọba 11:9
Oluwa si binu si Solomoni, nitori ọkàn rẹ̀ yipada kuro lọdọ Oluwa Ọlọrun Israeli, ti o ti fi ara hàn a lẹrinmeji.
Explore I. A. Ọba 11:9
Home
Bible
Plans
Videos