1
ORIN DAFIDI 70:4
Yoruba Bible
Kí gbogbo àwọn tí ń wá ọ máa yọ̀ nítorí rẹ, kí inú wọn sì máa dùn, kí àwọn tí ó fẹ́ràn ìgbàlà rẹ máa wí nígbà gbogbo pé, “Ọlọrun tóbi!”
Compare
Explore ORIN DAFIDI 70:4
2
ORIN DAFIDI 70:5
Ṣugbọn ní tèmi, olùpọ́njú ati aláìní ni mí, yára wá sọ́dọ̀ mi, Ọlọrun! Ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ mi ati olùgbàlà mi, má pẹ́ OLÚWA.
Explore ORIN DAFIDI 70:5
3
ORIN DAFIDI 70:1
Ọlọrun, dákun, gbà mí, yára, OLUWA, ràn mí lọ́wọ́.
Explore ORIN DAFIDI 70:1
Home
Bible
Plans
Videos