1
ORIN DAFIDI 68:19
Yoruba Bible
Ìyìn ni fún OLUWA, Ọlọrun ìgbàlà wa, tí ń bá wa gbé ẹrù wa lojoojumọ.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 68:19
2
ORIN DAFIDI 68:5
Baba àwọn aláìníbaba ati olùgbèjà àwọn opó ni Ọlọrun, ní ibùgbé rẹ̀ mímọ́.
Explore ORIN DAFIDI 68:5
3
ORIN DAFIDI 68:6
Ọlọrun, olùpèsè ibùjókòó fún àlejò tí ó nìkan wà; ẹni tí ó kó àwọn ẹlẹ́wọ̀n jáde sinu ìdẹ̀ra, ṣugbọn ó sì fi àwọn ọlọ̀tẹ̀ sílẹ̀ ninu ilẹ̀ gbígbẹ.
Explore ORIN DAFIDI 68:6
4
ORIN DAFIDI 68:20
Ọlọrun tí ń gbani là ni Ọlọrun wa; OLUWA Ọlọrun ni ń yọni lọ́wọ́ ikú.
Explore ORIN DAFIDI 68:20
Home
Bible
Plans
Videos