1
ORIN DAFIDI 63:1
Yoruba Bible
Ọlọrun, ìwọ ni Ọlọrun mi, mò ń wá ọ, ọkàn rẹ ń fà mí; bí ilẹ̀ tí ó ti ṣá, tí ó sì gbẹ ṣe máa ń kóǹgbẹ omi.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 63:1
2
ORIN DAFIDI 63:3
Nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ dára ju ìyè lọ, n óo máa yìn ọ́.
Explore ORIN DAFIDI 63:3
3
ORIN DAFIDI 63:4
N óo máa yìn ọ́ títí ayé mi; n óo máa tẹ́wọ́ adura sí ọ.
Explore ORIN DAFIDI 63:4
4
ORIN DAFIDI 63:2
Mo ti ń wò ọ́ ninu ilé mímọ́ rẹ, mo ti rí agbára ati ògo rẹ.
Explore ORIN DAFIDI 63:2
5
ORIN DAFIDI 63:7-8
nítorí ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ mi, lábẹ́ òjìji ìyẹ́ rẹ ni mò ń fi ayọ̀ kọrin. Ẹ̀mí mi rọ̀ mọ́ ọ; ọwọ́ ọ̀tun rẹ ni ó gbé mi ró.
Explore ORIN DAFIDI 63:7-8
6
ORIN DAFIDI 63:6
Nígbà tí mo bá ranti rẹ lórí ibùsùn mi, tí mo bá ń ṣe àṣàrò nípa rẹ ní gbogbo òru
Explore ORIN DAFIDI 63:6
Home
Bible
Plans
Videos