1
ORIN DAFIDI 149:4
Yoruba Bible
Nítorí pé inú OLUWA dùn sí àwọn eniyan rẹ̀, a sì máa fi ìṣẹ́gun dé àwọn onírẹ̀lẹ̀ ládé.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 149:4
2
ORIN DAFIDI 149:6
Kí wọn máa fi ohùn wọn yin Ọlọrun; kí idà olójú meji sì wà ní ọwọ́ wọn
Explore ORIN DAFIDI 149:6
3
ORIN DAFIDI 149:1
Ẹ yin OLUWA! Ẹ kọ orin titun sí OLUWA, ẹ kọrin ìyìn sí i ninu àwùjọ àwọn olóòótọ́.
Explore ORIN DAFIDI 149:1
Home
Bible
Plans
Videos