1
ORIN DAFIDI 136:1
Yoruba Bible
Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ OLUWA, nítorí pé ó ṣeun, nítorí pé ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 136:1
2
ORIN DAFIDI 136:26
Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọrun ọ̀run, nítorí pé ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae.
Explore ORIN DAFIDI 136:26
3
ORIN DAFIDI 136:2
Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọrun tí ó ju gbogbo àwọn oriṣa lọ, nítorí pé ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae.
Explore ORIN DAFIDI 136:2
4
ORIN DAFIDI 136:3
Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ OLUWA tí ó ju gbogbo àwọn oluwa lọ, nítorí pé ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae.
Explore ORIN DAFIDI 136:3
Home
Bible
Plans
Videos