1
ORIN DAFIDI 116:1-2
Yoruba Bible
Mo fẹ́ràn OLUWA nítorí pé ó gbọ́ adura ati ẹ̀bẹ̀ mi. Nítorí pé ó tẹ́tí sí mi, nítorí náà, n óo máa ké pè é níwọ̀n ìgbà tí mo bá wà láàyè.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 116:1-2
2
ORIN DAFIDI 116:5
Olóore ọ̀fẹ́ ati olódodo ni OLUWA, aláàánú ni Ọlọrun wa.
Explore ORIN DAFIDI 116:5
3
ORIN DAFIDI 116:15
Iyebíye ni ikú àwọn eniyan rẹ̀ mímọ́ lójú OLUWA.
Explore ORIN DAFIDI 116:15
4
ORIN DAFIDI 116:8-9
Nítorí ìwọ OLUWA ti gba ọkàn mi lọ́wọ́ ikú, o gba ojú mi lọ́wọ́ omijé, o sì gba ẹsẹ̀ mi lọ́wọ́ ìṣubú. Mò ń rìn níwájú OLUWA, lórí ilẹ̀ alààyè.
Explore ORIN DAFIDI 116:8-9
Home
Bible
Plans
Videos