1
LEFITIKU 6:13
Yoruba Bible
Iná orí pẹpẹ náà gbọdọ̀ máa jó nígbà gbogbo, kò gbọdọ̀ kú.
Compare
Explore LEFITIKU 6:13
2
LEFITIKU 6:12
Kí iná orí pẹpẹ náà sì máa jó, kò gbọdọ̀ kú nígbà kan. Kí alufaa máa kó igi sí i ní àràárọ̀; kí ó máa to ẹbọ sísun lé e lórí, orí rẹ̀ ni yóo sì ti máa sun ọ̀rá ẹran tí ó bá fi rú ẹbọ alaafia.
Explore LEFITIKU 6:12
Home
Bible
Plans
Videos