1
ẸKÚN JEREMAYA 3:22-23
Yoruba Bible
Nítorí pé Ìfẹ́ OLUWA tí kì í yẹ̀ kò nípẹ̀kun, àánú rẹ̀ kò sì lópin; ọ̀tun ni wọ́n láràárọ̀, òtítọ́ rẹ̀ pọ̀.
Compare
Explore ẸKÚN JEREMAYA 3:22-23
2
ẸKÚN JEREMAYA 3:24
Ọkàn mi wí pé, “OLUWA ni ìpín mi, nítorí náà lọ́dọ̀ rẹ̀ ni ìrètí mi wà.”
Explore ẸKÚN JEREMAYA 3:24
3
ẸKÚN JEREMAYA 3:25
OLUWA a máa ṣe oore fún àwọn tí wọn dúró dè é, tí wọn sì ń wá ojurere rẹ̀.
Explore ẸKÚN JEREMAYA 3:25
4
ẸKÚN JEREMAYA 3:40
Ẹ jẹ́ kí á yẹ ara wa wò, kí á tún ọ̀nà wa ṣe, kí á sì yipada sí ọ̀dọ̀ OLUWA.
Explore ẸKÚN JEREMAYA 3:40
5
ẸKÚN JEREMAYA 3:57
O súnmọ́ ọ̀dọ̀ mi nígbà tí mo pè ọ́, o dá mi lóhùn pé, ‘Má bẹ̀rù.’
Explore ẸKÚN JEREMAYA 3:57
Home
Bible
Plans
Videos