1
JOBU 27:3-4
Yoruba Bible
níwọ̀n ìgbà tí mo wà láàyè, tí mo sì ń mí, n kò ní fi ẹnu mi purọ́, ahọ́n mi kò sì ní sọ̀rọ̀ ẹ̀tàn.
Compare
Explore JOBU 27:3-4
2
JOBU 27:6
Mo dúró lórí òdodo mi láìyẹsẹ̀, ọkàn mi kò ní dá mi lẹ́bi, títí n óo fi kú.
Explore JOBU 27:6
Home
Bible
Plans
Videos