1
ISIKIẸLI 36:26
Yoruba Bible
N óo fun yín ní ọkàn titun, n óo sì fi ẹ̀mí titun si yín ninu. N óo yọ ọkàn tí ó le bí òkúta kúrò, n óo sì fun yín ní ọkàn tí ó rọ̀ bí ẹran ara.
Compare
Explore ISIKIẸLI 36:26
2
ISIKIẸLI 36:27
N óo fi ẹ̀mí mi si yín ninu, n óo mú kí ẹ máa rìn ní ìlànà mi, kí ẹ sì máa fi tọkàntọkàn pa òfin mi mọ́.
Explore ISIKIẸLI 36:27
3
ISIKIẸLI 36:25
N óo wọ́n omi mímọ́ si yín lórí, àìmọ́ yín yóo sì di mímọ́. N óo wẹ̀ yín mọ́ kúrò ninu gbogbo ìbọ̀rìṣà yín.
Explore ISIKIẸLI 36:25
4
ISIKIẸLI 36:28
Ẹ óo sì máa gbé orí ilẹ̀ tí mo fún àwọn baba ńlá yín. Ẹ óo jẹ́ eniyan mi, n óo sì máa jẹ́ Ọlọrun yín.
Explore ISIKIẸLI 36:28
Home
Bible
Plans
Videos