1
ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10:10
Yoruba Bible
Ẹni tí kò bá pọ́n àáké rẹ̀ kí ó mú, yóo lo agbára pupọ bí ó bá fẹ́ lò ó, ṣugbọn ọgbọ́n a máa ranni lọ́wọ́ láti ṣe àṣeyọrí.
Compare
Explore ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10:10
2
ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10:4
Bí aláṣẹ bá ń bínú sí ọ, má ṣe torí rẹ̀ kúrò ní ìdí iṣẹ́ rẹ, ìtẹríba lè mú kí wọn dárí ẹ̀ṣẹ̀ tí ó bá tóbi jini.
Explore ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10:4
3
ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10:1
Bí òkú eṣinṣin ṣe lè ba òórùn turari jẹ́; bẹ́ẹ̀ ni ìwà òmùgọ̀ kékeré lè ba ọgbọ́n ńlá ati iyì jẹ́.
Explore ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10:1
4
ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10:12
Ọ̀rọ̀ ẹnu ọlọ́gbọ́n a máa bu iyì kún un, ṣugbọn ẹnu òmùgọ̀ ni yóo pa á.
Explore ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10:12
5
ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10:8
Ẹni tí ó gbẹ́ kòtò ni yóo jìn sinu rẹ̀, ẹni tí ó bá já ọgbà wọlé ni ejò yóo bùjẹ.
Explore ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 10:8
Home
Bible
Plans
Videos