1
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 17:27
Yoruba Bible
Ó dá wọn láti máa wá òun Ọlọrun, bí ó bá ṣeéṣe, kí wọ́n fọwọ́ kàn án, kí wọ́n rí i. Kò sì kúkú jìnnà sí ẹnìkan kan ninu wa.
Compare
Explore ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 17:27
2
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 17:26
Òun ni ó dá gbogbo orílẹ̀-èdè láti inú ẹnìkan ṣoṣo láti máa gbé gbogbo ilẹ̀ ayé. Kí ó tó dá wọn, ó ti ṣe ìpinnu tẹ́lẹ̀ nípa ìgbà tí wọn yóo gbé ní ayé ati ààlà ibi tí wọn yóo máa gbé.
Explore ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 17:26
3
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 17:24
Ọlọrun tí ó dá ayé ati gbogbo nǹkan tí ó wà ninu rẹ̀, Oluwa ọ̀run ati ayé, kì í gbé ilé oriṣa àfọwọ́kọ́
Explore ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 17:24
4
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 17:31
Nítorí ó ti yan ọjọ́ tí yóo fi òdodo ṣe ìdájọ́ gbogbo ayé nípa ọkunrin tí ó ti yàn. Ó fi òtítọ́ èyí han gbogbo eniyan nígbà tí ó jí ẹni náà dìde kúrò ninu òkú.”
Explore ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 17:31
5
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 17:29
Nígbà tí a jẹ́ ọmọ Ọlọrun, kò yẹ kí á rò pé Ọlọrun dàbí ère wúrà, tabi fadaka, tabi òkúta, ère tí oníṣẹ́ ọnà ṣe pẹlu ọgbọ́n ati èrò eniyan.
Explore ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 17:29
Home
Bible
Plans
Videos