1
ÀWỌN ỌBA KEJI 6:17
Yoruba Bible
Eliṣa bá gbadura pé kí OLUWA jọ̀wọ́ ṣí ojú rẹ̀, kí ó lè ríran. OLUWA ṣí iranṣẹ náà lójú, ó sì rí i pé gbogbo orí òkè náà kún fún ẹṣin ati kẹ̀kẹ́ ogun, iná sí yí Eliṣa ká.
Compare
Explore ÀWỌN ỌBA KEJI 6:17
2
ÀWỌN ỌBA KEJI 6:16
Eliṣa dáhùn pé, “Má bẹ̀rù nítorí pé àwọn tí wọ́n wà pẹlu wa ju àwọn tí wọ́n wà pẹlu wọn lọ.”
Explore ÀWỌN ỌBA KEJI 6:16
3
ÀWỌN ỌBA KEJI 6:15
Ní òwúrọ̀ kutukutu, nígbà tí iranṣẹ Eliṣa jáde sí ìta, ó rí i pé àwọn ọmọ ogun Siria ti yí ìlú náà po pẹlu ẹṣin ati àwọn kẹ̀kẹ́-ogun. Ó pada wọlé tọ Eliṣa lọ, ó sì kígbe pé, “Yéè, oluwa mi, kí ni a óo ṣe?”
Explore ÀWỌN ỌBA KEJI 6:15
4
ÀWỌN ỌBA KEJI 6:18
Nígbà tí àwọn ará Siria gbìyànjú láti mú un, ó gbadura pé kí OLUWA jọ̀wọ́ fọ́ àwọn ọkunrin náà lójú. OLUWA sì fọ́ wọn lójú gẹ́gẹ́ bí adura Eliṣa.
Explore ÀWỌN ỌBA KEJI 6:18
5
ÀWỌN ỌBA KEJI 6:6
Eliṣa bèèrè pé, “Níbo ni ó bọ́ sí?” Ọkunrin náà sì fi ibẹ̀ hàn án. Eliṣa gé igi kan, ó jù ú sinu omi, irin àáké náà sì léfòó lójú omi.
Explore ÀWỌN ỌBA KEJI 6:6
6
ÀWỌN ỌBA KEJI 6:5
Bí ọ̀kan ninu wọn ti ń gé igi, lójijì, irin àáké tí ó ń lò yọ bọ́ sinu odò. Ó kígbe pé, “Yéè! Oluwa mi, a yá àáké yìí ni!”
Explore ÀWỌN ỌBA KEJI 6:5
7
ÀWỌN ỌBA KEJI 6:7
Eliṣa pàṣẹ fún un pé, “Mú un.” Ọkunrin náà bá mu irin àáké náà.
Explore ÀWỌN ỌBA KEJI 6:7
Home
Bible
Plans
Videos