1
ÀWỌN ỌBA KEJI 13:21
Yoruba Bible
Ní ìgbà kan, bí wọ́n ti fẹ́ máa sìnkú ọkunrin kan, wọ́n rí i tí àwọn ọmọ ogun Moabu ń bọ̀, wọ́n bá ju òkú náà sinu ibojì Eliṣa. Bí ọkunrin náà ti fi ara kan egungun Eliṣa, ó sọjí, ó sì dúró lórí ẹsẹ̀ rẹ̀.
Compare
Explore ÀWỌN ỌBA KEJI 13:21
Home
Bible
Plans
Videos