1
KỌRINTI KEJI 8:9
Yoruba Bible
Nítorí ẹ mọ oore-ọ̀fẹ́ Oluwa wa Jesu Kristi, pé nítorí tiwa, òun tí ó jẹ́ ọlọ́rọ̀ di aláìní, kí ẹ lè di ọlọ́rọ̀ nípa àìní tirẹ̀.
Compare
Explore KỌRINTI KEJI 8:9
2
KỌRINTI KEJI 8:2
Wọ́n ní ọpọlọpọ ìdánwò nípa ìpọ́njú. Sibẹ wọ́n ní ayọ̀ pupọ. Wọ́n ṣe aláìní pupọ, sibẹ wọ́n lawọ́ gan-an.
Explore KỌRINTI KEJI 8:2
Home
Bible
Plans
Videos