1
ÀWỌN ỌBA KINNI 4:29
Yoruba Bible
Ọgbọ́n ati òye tí Ọlọrun fún Solomoni kọjá sísọ, ìmọ̀ rẹ̀ sì kọjá ìwọ̀n.
Compare
Explore ÀWỌN ỌBA KINNI 4:29
2
ÀWỌN ỌBA KINNI 4:34
Àwọn eniyan sì ń wá láti oniruuru orílẹ̀ èdè, ati láti ọ̀dọ̀ àwọn ọba ní gbogbo ayé, tí wọ́n ti gbúròó nípa ọgbọ́n rẹ̀, wọn á wá tẹ́tí sí ọgbọ́n rẹ̀.
Explore ÀWỌN ỌBA KINNI 4:34
Home
Bible
Plans
Videos