1
KRONIKA KINNI 16:11
Yoruba Bible
OLUWA ni kí ẹ máa tọ̀ lọ fún ìrànlọ́wọ́, Ẹ máa sìn ín nígbà gbogbo.
Compare
Explore KRONIKA KINNI 16:11
2
KRONIKA KINNI 16:34
Ẹ fi ọpẹ́ fún OLUWA nítorí pé ó ṣeun, ìfẹ́ rẹ̀ tí kìí yẹ̀ sì wà títí lae!
Explore KRONIKA KINNI 16:34
3
KRONIKA KINNI 16:8
Ẹ fi ọpẹ́ fún OLUWA, ẹ képe orúkọ rẹ̀, ẹ kéde ohun tí ó ti ṣe fún àwọn orílẹ̀-èdè.
Explore KRONIKA KINNI 16:8
4
KRONIKA KINNI 16:10
Ẹ máa fi orúkọ rẹ̀ ṣògo, kí ọkàn àwọn tí wọn ń sin OLUWA kún fún ayọ̀.
Explore KRONIKA KINNI 16:10
5
KRONIKA KINNI 16:12
Ẹ ranti gbogbo iṣẹ́ ìyanu rẹ̀, gbogbo nǹkan ìyanu tí ó ṣe, ati gbogbo ìdájọ́ rẹ̀
Explore KRONIKA KINNI 16:12
6
KRONIKA KINNI 16:9
Ẹ kọrin sí i, ẹ kọrin ìyìn sí i, ẹ sọ nípa àwọn ohun ìyanu tí ó ṣe!
Explore KRONIKA KINNI 16:9
7
KRONIKA KINNI 16:25
OLUWA tóbi, ìyìn tọ́ sí i lọpọlọpọ ó sì yẹ kí á bọ̀wọ̀ fún un ju gbogbo àwọn oriṣa lọ.
Explore KRONIKA KINNI 16:25
8
KRONIKA KINNI 16:29
Ẹ fi ògo tí ó yẹ orúkọ OLUWA fún un, ẹ mú ọrẹ wá sí iwájú rẹ̀! Ẹ sin OLUWA pẹlu ẹwà mímọ́
Explore KRONIKA KINNI 16:29
9
KRONIKA KINNI 16:27
Ògo ati agbára yí i ká, ayọ̀ ati ìyìn sì kún Tẹmpili rẹ̀.
Explore KRONIKA KINNI 16:27
10
KRONIKA KINNI 16:23
Ẹ kọrin sí OLUWA, gbogbo ayé! Ẹ máa kéde ìgbàlà rẹ̀ lojoojumọ.
Explore KRONIKA KINNI 16:23
11
KRONIKA KINNI 16:24
Ẹ kéde ògo rẹ̀ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè, ẹ polongo iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ láàrin àwọn eniyan!
Explore KRONIKA KINNI 16:24
12
KRONIKA KINNI 16:22
Ó ní, “Ẹ má ṣe fi ọwọ́ kan àwọn ẹni àmì òróró mi, ẹ má sì pa àwọn wolii mi lára!”
Explore KRONIKA KINNI 16:22
13
KRONIKA KINNI 16:26
Nítorí pé ère lásán ni àwọn orílẹ̀-èdè yòókù sọ di ọlọrun, ṣugbọn OLUWA ló dá ọ̀run.
Explore KRONIKA KINNI 16:26
14
KRONIKA KINNI 16:15
Kò ní í gbàgbé majẹmu rẹ̀ títí lae, àní àwọn ohun tí ó ti pa láṣẹ láti ṣe fún ẹgbẹẹgbẹrun ìran
Explore KRONIKA KINNI 16:15
15
KRONIKA KINNI 16:31
Kí inú ọ̀run kí ó dùn, kí ayé kí ó yọ̀, kí wọ́n sọ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè pé “OLUWA jọba!”
Explore KRONIKA KINNI 16:31
16
KRONIKA KINNI 16:36
Ẹni ìyìn ni OLUWA, Ọlọrun Israẹli, lae ati laelae!” Gbogbo àwọn eniyan sì dáhùn pe, “Amin”, wọ́n sì yin OLUWA.
Explore KRONIKA KINNI 16:36
17
KRONIKA KINNI 16:28
Ẹ fi ògo fún OLUWA, gbogbo ayé, ẹ gbé ògo ati agbára wọ̀ ọ́!
Explore KRONIKA KINNI 16:28
Home
Bible
Plans
Videos