Лого на YouVersion
Иконка за търсене

Gẹnẹsisi 14:22-23

Gẹnẹsisi 14:22-23 YCB

Ṣùgbọ́n Abramu dá ọba Sodomu lóhùn pé, “Mo ti búra fún OLúWA, Ọlọ́run Ọ̀gá-ògo, tí ó dá ọ̀run àti ayé, mo sì ti gbọ́wọ́ sókè, pé, èmi kì yóò mú láti fọ́nrán òwú títí dé okùn bàtà, àti pé, èmi kí yóò mú ohun kan tí ṣe tìrẹ, kí ìwọ kí ó má ba à wí pé, ‘Mo sọ Abramu di ọlọ́rọ̀.’