1
Gẹnẹsisi 16:13
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ó sì pe orúkọ OLúWA tí o bá sọ̀rọ̀ ní, “Ìwọ ni Ọlọ́run tí ó rí mi,” nítorí tí ó wí pé, “Mo ti ri ẹni tí ó rí mi báyìí.”
Сравни
Разгледайте Gẹnẹsisi 16:13
2
Gẹnẹsisi 16:11
Angẹli OLúWA náà sì wí fún un pé, “Ìwọ ti lóyún, ìwọ yóò sì bí ọmọkùnrin kan, ìwọ yóò sì pe orúkọ rẹ̀ ní Iṣmaeli, nítorí tí OLúWA ti rí ìpọ́njú rẹ.
Разгледайте Gẹnẹsisi 16:11
3
Gẹnẹsisi 16:12
Òun yóò jẹ́ oníjàgídíjàgan ènìyàn ọwọ́ rẹ̀ yóò wà lára ènìyàn gbogbo, ọwọ́ ènìyàn gbogbo yóò sì wà lára rẹ̀, yóò sì máa gbé ní ìkanra pẹ̀lú àwọn arákùnrin rẹ̀.”
Разгледайте Gẹnẹsisi 16:12
Начало
Библия
Планове
Видеа